Jeremáyà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ kéde rẹ̀ ní Júdà, ẹ sì polongo rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù. Ẹ kígbe, kí ẹ sì fun ìwo jákèjádò ilẹ̀ náà.+ Ẹ gbóhùn sókè, kí ẹ sì sọ pé: “Ẹ kóra jọ,Ẹ sì jẹ́ kí a sá wọ àwọn ìlú olódi.+ Hósíà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+
5 Ẹ kéde rẹ̀ ní Júdà, ẹ sì polongo rẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù. Ẹ kígbe, kí ẹ sì fun ìwo jákèjádò ilẹ̀ náà.+ Ẹ gbóhùn sókè, kí ẹ sì sọ pé: “Ẹ kóra jọ,Ẹ sì jẹ́ kí a sá wọ àwọn ìlú olódi.+
8 “Fi ìwo sí ẹnu rẹ!+ Ọ̀tá kan ń bọ̀ bí ẹyẹ idì sí ilé Jèhófà,+Torí pé wọ́n ti da májẹ̀mú mi,+ wọ́n sì ti rú òfin mi.+