Jeremáyà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+ Jeremáyà 25:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo ilẹ̀ yìí á di àwókù àti ohun àríbẹ̀rù, àwọn orílẹ̀-èdè yìí á sì ní láti fi àádọ́rin (70) ọdún sin ọba Bábílónì.”’+
11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+
11 Gbogbo ilẹ̀ yìí á di àwókù àti ohun àríbẹ̀rù, àwọn orílẹ̀-èdè yìí á sì ní láti fi àádọ́rin (70) ọdún sin ọba Bábílónì.”’+