Dáníẹ́lì 2:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+ Dáníẹ́lì 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “PÉRÉSÌ, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mídíà àti Páṣíà.”+ Dáníẹ́lì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí mo gbé ojú mi sókè, wò ó! àgbò+ kan dúró níwájú ipadò náà, ó sì ní ìwo méjì.+ Ìwo méjèèjì ga, àmọ́ ọ̀kan ga ju ìkejì lọ, èyí tó ga jù sì jáde wá lẹ́yìn náà.+ Dáníẹ́lì 8:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Àgbò oníwo méjì tí o rí dúró fún àwọn ọba Mídíà àti Páṣíà.+
39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+
3 Nígbà tí mo gbé ojú mi sókè, wò ó! àgbò+ kan dúró níwájú ipadò náà, ó sì ní ìwo méjì.+ Ìwo méjèèjì ga, àmọ́ ọ̀kan ga ju ìkejì lọ, èyí tó ga jù sì jáde wá lẹ́yìn náà.+