Sáàmù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ọba ayé dúróÀwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+ Jòhánù 1:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ó kọ́kọ́ wá Símónì arákùnrin rẹ̀, ó sì sọ fún un pé: “A ti rí Mèsáyà náà”+ (tó túmọ̀ sí “Kristi”),
41 Ó kọ́kọ́ wá Símónì arákùnrin rẹ̀, ó sì sọ fún un pé: “A ti rí Mèsáyà náà”+ (tó túmọ̀ sí “Kristi”),