-
Lúùkù 18:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ṣùgbọ́n, ìkankan nínú àwọn ọ̀rọ̀ yìí ò yé wọn, torí wọn ò mọ ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ yìí, wọn ò sì lóye ohun tó sọ.
-
-
1 Pétérù 1:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ní ti ìgbàlà yìí, àwọn wòlíì tí wọ́n sọ tẹ́lẹ̀ nípa inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tó jẹ́ tiyín, fara balẹ̀ wádìí, wọ́n sì fẹ̀sọ̀ wá a.+ 11 Wọn ò yéé wádìí àkókò náà gan-an tàbí ìgbà tí ẹ̀mí tó wà nínú wọn ń tọ́ka sí nípa Kristi,+ bó ṣe jẹ́rìí ṣáájú nípa àwọn ìyà tí Kristi máa jẹ+ àti ògo tó máa tẹ̀ lé e.
-