Diutarónómì 32:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ká sọ pé wọ́n gbọ́n ni!+ Wọn ì bá ro ọ̀rọ̀ yìí dáadáa.+ Kí wọ́n ro ibi tó máa já sí.+ Àìsáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.” Émọ́sì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà ti fi Ògo Jékọ́bù+ búra,‘Mi ò ní gbàgbé gbogbo ohun tí wọ́n ṣe.+
3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”