Hósíà 4:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Bí o tilẹ̀ ń ṣe ìṣekúṣe,* ìwọ Ísírẹ́lì,+Má ṣe jẹ́ kí Júdà jẹ̀bi.+ Má ṣe wá sí Gílígálì+ tàbí Bẹti-áfénì,+Má sì ṣe búra pé, ‘Bí Jèhófà ti wà láàyè!’+ Hósíà 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+ Émọ́sì 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ má ṣe wá Bẹ́tẹ́lì kiri,+Ẹ má lọ sí Gílígálì,+ ẹ má sì kọjá sí Bíá-ṣébà,+Torí ó dájú pé Gílígálì máa lọ sí ìgbèkùn,+Bẹ́tẹ́lì á sì di asán.*
15 Bí o tilẹ̀ ń ṣe ìṣekúṣe,* ìwọ Ísírẹ́lì,+Má ṣe jẹ́ kí Júdà jẹ̀bi.+ Má ṣe wá sí Gílígálì+ tàbí Bẹti-áfénì,+Má sì ṣe búra pé, ‘Bí Jèhófà ti wà láàyè!’+
11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+
5 Ẹ má ṣe wá Bẹ́tẹ́lì kiri,+Ẹ má lọ sí Gílígálì,+ ẹ má sì kọjá sí Bíá-ṣébà,+Torí ó dájú pé Gílígálì máa lọ sí ìgbèkùn,+Bẹ́tẹ́lì á sì di asán.*