Hósíà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Gílígálì + ni gbogbo ìwà ibi wọn ti ṣẹlẹ̀, ibẹ̀ ni mo ti kórìíra wọn. Màá lé wọn kúrò ní ilé mi nítorí iṣẹ́ ibi wọn.+ Mi ò ní nífẹ̀ẹ́ wọn mọ́;+Gbogbo olórí wọn ya alágídí. Hósíà 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+ Émọ́sì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 ‘Ẹ wá sí Bẹ́tẹ́lì, kí ẹ sì dẹ́ṣẹ̀,*+Àti sí Gílígálì kí ẹ dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀!+ Ẹ mú àwọn ẹbọ yín wá+ ní òwúrọ̀,Ẹ sì mú ìdá mẹ́wàá+ yín wá ní ọjọ́ kẹta.
15 “Gílígálì + ni gbogbo ìwà ibi wọn ti ṣẹlẹ̀, ibẹ̀ ni mo ti kórìíra wọn. Màá lé wọn kúrò ní ilé mi nítorí iṣẹ́ ibi wọn.+ Mi ò ní nífẹ̀ẹ́ wọn mọ́;+Gbogbo olórí wọn ya alágídí.
11 Ẹ̀tàn*+ àti àìṣòótọ́ ti wà ní Gílíádì. Wọ́n ti fi àwọn akọ màlúù rúbọ ní Gílígálì,+Àwọn pẹpẹ wọn sì dà bí àwọn òkúta tí a tò jọ sí àárín àwọn ebè inú oko.+
4 ‘Ẹ wá sí Bẹ́tẹ́lì, kí ẹ sì dẹ́ṣẹ̀,*+Àti sí Gílígálì kí ẹ dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀!+ Ẹ mú àwọn ẹbọ yín wá+ ní òwúrọ̀,Ẹ sì mú ìdá mẹ́wàá+ yín wá ní ọjọ́ kẹta.