Diutarónómì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o ṣe. Ó mọ gbogbo bí o ṣe ń rìn nínú aginjù tó tóbi yìí dáadáa. Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti wà pẹ̀lú rẹ jálẹ̀ ogójì (40) ọdún yìí, o ò sì ṣaláìní ohunkóhun.”’+ Diutarónómì 32:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. 10 Ó rí i nínú aginjù,+Ní aṣálẹ̀,+ tó ṣófo, tó ń hu. Ó yí i ká kó lè dáàbò bò ó, ó tọ́jú rẹ̀,+Ó sì ṣọ́ ọ bí ọmọlójú+ rẹ̀.
7 Torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti bù kún ọ nínú gbogbo ohun tí o ṣe. Ó mọ gbogbo bí o ṣe ń rìn nínú aginjù tó tóbi yìí dáadáa. Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti wà pẹ̀lú rẹ jálẹ̀ ogójì (40) ọdún yìí, o ò sì ṣaláìní ohunkóhun.”’+
9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. 10 Ó rí i nínú aginjù,+Ní aṣálẹ̀,+ tó ṣófo, tó ń hu. Ó yí i ká kó lè dáàbò bò ó, ó tọ́jú rẹ̀,+Ó sì ṣọ́ ọ bí ọmọlójú+ rẹ̀.