Nọ́ńbà 34:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé. Nọ́ńbà 34:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí ẹ pààlà yín láti Òkè Hóórì dé Lebo-hámátì,*+ kí ààlà náà sì parí sí Sédádì.+ 2 Àwọn Ọba 14:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ní ti ìyókù ìtàn Jèróbóámù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti agbára rẹ̀, bí ó ṣe jà àti bí ó ṣe gba Damásíkù+ àti Hámátì+ pa dà fún Júdà ní Ísírẹ́lì, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Ísírẹ́lì?
2 “Fi ìtọ́ni yìí tó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì létí pé, ‘Tí ẹ bá wọ ilẹ̀ Kénáánì,+ ilẹ̀ tó máa di tiyín nìyí láwọn ibi tí ààlà+ rẹ̀ dé.
28 Ní ti ìyókù ìtàn Jèróbóámù àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti agbára rẹ̀, bí ó ṣe jà àti bí ó ṣe gba Damásíkù+ àti Hámátì+ pa dà fún Júdà ní Ísírẹ́lì, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Ísírẹ́lì?