-
1 Àwọn Ọba 14:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Yóò pa Ísírẹ́lì tì nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí Jèróbóámù dá àti èyí tó mú kí Ísírẹ́lì dá.”+
-
-
2 Àwọn Ọba 16:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ẹni ogún (20) ọdún ni Áhásì nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Kò ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ bí Dáfídì baba ńlá rẹ̀ ti ṣe.+ 3 Kàkà bẹ́ẹ̀, ó rìn ní ọ̀nà àwọn ọba Ísírẹ́lì,+ kódà ó sun ọmọ rẹ̀ nínú iná,+ ó tipa bẹ́ẹ̀ ṣe ohun ìríra tí àwọn orílẹ̀-èdè+ tí Jèhófà lé kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń ṣe.
-