ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 23:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Orúkọ ẹ̀gbọ́n ni Òhólà,* orúkọ àbúrò rẹ̀ sì ni Òhólíbà.* Wọ́n di tèmi, wọ́n sì bí àwọn ọmọ ọkùnrin àti obìnrin. Èyí tó ń jẹ́ Òhólà ni Samáríà,+ èyí tó sì ń jẹ́ Òhólíbà ni Jerúsálẹ́mù.

      5 “Nígbà tí Òhólà ṣì jẹ́ tèmi, ó bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe aṣẹ́wó.+ Ọkàn rẹ̀ fà sí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ àtàtà,+ àwọn ará Ásíríà tó jẹ́ aládùúgbò rẹ̀ kó lè bá wọn ṣèṣekúṣe.+

  • Ìsíkíẹ́lì 23:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Torí náà, mo mú kí ọwọ́ àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ àtàtà tẹ̀ ẹ́, àwọn ọmọ Ásíríà+ tí ọkàn rẹ̀ fà sí.

  • Hósíà 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ẹ fẹ̀sùn kan ìyá yín; ẹ fẹ̀sùn kàn án,

      Torí kì í ṣe aya mi,+ èmi kì í sì í ṣe ọkọ rẹ̀.

      Kí ó jáwọ́ nínú ìṣekúṣe* rẹ̀

      Kí ó sì mú ìwà àgbèrè kúrò láàárín ọmú rẹ̀,

  • Hósíà 9:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “Gílígálì + ni gbogbo ìwà ibi wọn ti ṣẹlẹ̀, ibẹ̀ ni mo ti kórìíra wọn.

      Màá lé wọn kúrò ní ilé mi nítorí iṣẹ́ ibi wọn.+

      Mi ò ní nífẹ̀ẹ́ wọn mọ́;+

      Gbogbo olórí wọn ya alágídí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́