ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 15:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Púlì+ ọba Ásíríà wá sí ilẹ̀ náà, Ménáhémù sì fún Púlì ní ẹgbẹ̀rún kan (1,000) tálẹ́ńtì* fàdákà nítorí ó tì í lẹ́yìn kí ìjọba má bàa bọ́ mọ́ ọn lọ́wọ́.+

  • 2 Àwọn Ọba 17:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ṣálímánésà ọba Ásíríà wá gbéjà ko Hóṣéà,+ Hóṣéà sì di ìránṣẹ́ rẹ̀, ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í san ìṣákọ́lẹ̀* fún Ṣálímánésà.+

  • Hósíà 5:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nígbà tí Éfúrémù rí i pé òun ń ṣàìsàn, tí Júdà sì rí i pé egbò wà lára òun,

      Éfúrémù lọ sí Ásíríà,+ ó sì ránṣẹ́ sí ọba ńlá.

      Ṣùgbọ́n kò lè mú un lára dá,

      Kò sì lè wo egbò rẹ̀ sàn.

  • Hósíà 7:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Éfúrémù dà bí àdàbà tó gọ̀, tí kò ní làákàyè.*+

      Wọ́n ti ké pe Íjíbítì;+ wọ́n ti lọ sí Ásíríà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́