ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 20:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọmọ Ísírẹ́lì àti àjèjì èyíkéyìí tó ń gbé ní Ísírẹ́lì tó bá fún Mólékì ní ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ̀.+ Kí àwọn èèyàn ilẹ̀ náà sọ ọ́ lókùúta pa. 3 Èmi fúnra mi kò ní fi ojú rere wo ọkùnrin yẹn, màá sì pa á, kí n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀, torí ó ti fún Mólékì lára àwọn ọmọ rẹ̀, ó ti sọ ibi mímọ́+ mi di ẹlẹ́gbin, ó sì ti sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́.

  • 2 Kíróníkà 33:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+

  • 2 Kíróníkà 33:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ó sun àwọn ọmọ rẹ̀ nínú iná+ ní Àfonífojì Ọmọ Hínómù;+ ó ń pidán,+ ó ń woṣẹ́, ó ń ṣe oṣó, ó sì yan àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́.+ Ohun búburú tó pọ̀ gan-an ló ṣe lójú Jèhófà, ó sì tipa bẹ́ẹ̀ mú un bínú.

  • Jeremáyà 7:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Wọ́n ti kọ́ àwọn ibi gíga Tófétì, èyí tó wà ní Àfonífojì Ọmọ Hínómù,*+ láti sun àwọn ọmọkùnrin wọn àti àwọn ọmọbìnrin wọn nínú iná,+ ohun tí mi ò pa láṣẹ, tí kò sì wá sí mi lọ́kàn rí.’*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́