Sáàmù 77:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọsánmà da omi sílẹ̀. Ojú ọ̀run tó ṣú dẹ̀dẹ̀ sán ààrá,Àwọn ọfà rẹ sì ń fò síbí sọ́hùn-ún.+ 18 Ìró ààrá rẹ+ dà bí ìró àgbá kẹ̀kẹ́ ẹṣin;Mànàmáná tó ń kọ mú kí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé* mọ́lẹ̀;+Ayé mì tìtì, ó sì mì jìgìjìgì.+
17 Àwọsánmà da omi sílẹ̀. Ojú ọ̀run tó ṣú dẹ̀dẹ̀ sán ààrá,Àwọn ọfà rẹ sì ń fò síbí sọ́hùn-ún.+ 18 Ìró ààrá rẹ+ dà bí ìró àgbá kẹ̀kẹ́ ẹṣin;Mànàmáná tó ń kọ mú kí ilẹ̀ ayé tí à ń gbé* mọ́lẹ̀;+Ayé mì tìtì, ó sì mì jìgìjìgì.+