Ẹ́kísódù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+ 2 Sámúẹ́lì 22:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì síwá-sẹ́yìn, ó sì ń mì jìgìjìgì;+Àwọn ìpìlẹ̀ ọ̀run mì tìtì+Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+
18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+
8 Ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì síwá-sẹ́yìn, ó sì ń mì jìgìjìgì;+Àwọn ìpìlẹ̀ ọ̀run mì tìtì+Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+