-
Sáàmù 18:7-12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà náà, ayé bẹ̀rẹ̀ sí í mì, ó sì ń mì jìgìjìgì;+
Ìpìlẹ̀ àwọn òkè mì,
Wọ́n sì ń mì síwá-sẹ́yìn nítorí a ti mú un bínú.+
9 Ó tẹ ọ̀run wálẹ̀ bí ó ṣe ń sọ̀ kalẹ̀.+
Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+
10 Ó gun kérúbù, ó sì ń fò bọ̀.+
Ó ń bọ̀ ṣòòrò wálẹ̀ lórí ìyẹ́ apá áńgẹ́lì kan.*+
12 Láti inú ìmọ́lẹ̀ tó wà níwájú rẹ̀,
Yìnyín àti ẹyin iná gba inú àwọsánmà jáde.
-