Sáàmù 104:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó tẹ́ igi àjà àwọn yàrá òkè rẹ̀ sínú omi lókè,*+Ó fi àwọsánmà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀,+Ó ń lọ lórí ìyẹ́ apá ẹ̀fúùfù.+ Hébérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+
3 Ó tẹ́ igi àjà àwọn yàrá òkè rẹ̀ sínú omi lókè,*+Ó fi àwọsánmà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀,+Ó ń lọ lórí ìyẹ́ apá ẹ̀fúùfù.+
7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+