Sáàmù 50:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí o kórìíra ìbáwí,*O sì ń kọ ẹ̀yìn sí ọ̀rọ̀ mi.*+ Àìsáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ibo la tún lè lù lára yín nígbà tí ẹ kò jáwọ́ nínú ìwà ọ̀tẹ̀ yín?+ Gbogbo orí yín ló ń ṣàìsànÀrùn sì ti kọ lu gbogbo ọkàn yín.+ Jeremáyà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+
5 Ibo la tún lè lù lára yín nígbà tí ẹ kò jáwọ́ nínú ìwà ọ̀tẹ̀ yín?+ Gbogbo orí yín ló ń ṣàìsànÀrùn sì ti kọ lu gbogbo ọkàn yín.+
3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+