ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Torí náà ni òjò kò fi rọ̀,+

      Tí kò sì sí òjò ní ìgbà ìrúwé.

      O rí bí* ọ̀dájú ìyàwó tó ń ṣe aṣẹ́wó;

      O ò ní ìtìjú.+

  • Jeremáyà 8:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ǹjẹ́ ojú tì wọ́n nítorí àwọn ohun ìríra tí wọ́n ṣe?

      Ojú kì í tì wọ́n!

      Àní wọn ò tiẹ̀ lójútì rárá!+

      Torí náà, wọ́n á ṣubú láàárín àwọn tó ti ṣubú.

      Nígbà tí mo bá fìyà jẹ wọ́n, wọ́n á kọsẹ̀,’+ ni Jèhófà wí.

  • Sefanáyà 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ẹ kóra jọ, bẹ́ẹ̀ ni, ẹ kó ara yín jọ,+

      Ẹ̀yin èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò ní ìtìjú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́