ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 60:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Torí orílẹ̀-èdè àti ìjọba èyíkéyìí tí kò bá sìn ọ́ máa ṣègbé,

      Àwọn orílẹ̀-èdè sì máa pa run pátápátá.+

  • Dáníẹ́lì 2:44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 44 “Ní ọjọ́ àwọn ọba yẹn, Ọlọ́run ọ̀run máa gbé ìjọba kan kalẹ̀,+ tí kò ní pa run láé.+ A ò ní gbé ìjọba yìí fún èèyàn èyíkéyìí míì.+ Ó máa fọ́ àwọn ìjọba yìí túútúú,+ ó máa fòpin sí gbogbo wọn, òun nìkan ló sì máa dúró títí láé,+

  • Sefanáyà 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 ‘Nítorí náà, ẹ máa retí mi,’*+ ni Jèhófà wí,

      ‘Títí di ọjọ́ tí màá wá gba* ohun tí ẹ ti gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn,

      Nítorí ìdájọ́ mi ni láti kó àwọn orílẹ̀-èdè jọ, kí n sì kó àwọn ìjọba jọ,

      Kí n lè da ìrunú mi sórí wọn, gbogbo ìbínú mi tó ń jó fòfò;+

      Torí ìtara mi tó ń jó bí iná máa jó gbogbo ayé run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́