7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;
Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+
Òní ni mo di bàbá rẹ.+
8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọ
Màá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+
9 Wàá fi ọ̀pá àṣẹ onírin+ ṣẹ́ wọn,
Wàá sì fọ́ wọn túútúú bí ìkòkò amọ̀.”+