Léfítíkù 26:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 èmi yóò rọ ọ̀wààrà òjò fún yín ní àkókò tó yẹ,+ ilẹ̀ yóò mú èso jáde,+ àwọn igi oko yóò sì so èso. Diutarónómì 28:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ìbùkún ni fún àwọn ọmọ*+ rẹ àti èso ilẹ̀ rẹ àtàwọn ọmọ ẹran ọ̀sìn rẹ, ọmọ màlúù àti àgùntàn+ rẹ. Àìsáyà 30:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+
23 Ó máa rọ òjò sí ohun tí o gbìn sínú ilẹ̀,+ oúnjẹ tí ilẹ̀ bá sì mú jáde máa pọ̀ rẹpẹtẹ, ó sì máa lọ́ràá.*+ Ní ọjọ́ yẹn, ẹran ọ̀sìn rẹ máa jẹko ní àwọn pápá tó fẹ̀.+