Ẹ́kísódù 23:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Màá pààlà fún yín láti Òkun Pupa dé òkun àwọn Filísínì àti láti aginjù dé Odò;*+ torí màá mú kí ọwọ́ yín tẹ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà, ẹ ó sì lé wọn kúrò níwájú yín.+ Sáàmù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+ Sáàmù 72:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Yóò ní àwọn ọmọ abẹ́* láti òkun dé òkunÀti láti Odò* dé àwọn ìkángun ayé.+
31 “Màá pààlà fún yín láti Òkun Pupa dé òkun àwọn Filísínì àti láti aginjù dé Odò;*+ torí màá mú kí ọwọ́ yín tẹ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà, ẹ ó sì lé wọn kúrò níwájú yín.+
8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+