Jóẹ́lì 2:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀+Kí ọjọ́ ńlá Jèhófà tó ń bani lẹ́rù tó dé.+ Ìṣe 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀, kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ olókìkí Jèhófà* tó dé. 2 Pétérù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+
10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+