14 Ó wá kó àwọn méjìlá (12) jọ,* ó tún pè wọ́n ní àpọ́sítélì, àwọn yìí ló máa wà pẹ̀lú rẹ̀, tó sì máa rán lọ wàásù, 15 wọ́n máa ní àṣẹ láti lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.+
9Ó wá pe àwọn Méjìlá náà jọ, ó fún wọn ní agbára àti àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀mí èṣù,+ kí wọ́n sì máa ṣe ìwòsàn.+2 Ó rán wọn jáde láti wàásù Ìjọba Ọlọ́run, kí wọ́n sì máa múni lára dá,