Lúùkù 1:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Áńgẹ́lì náà dá a lóhùn pé: “Ẹ̀mí mímọ́ máa bà lé ọ,+ agbára Ẹni Gíga Jù Lọ sì máa ṣíji bò ọ́. Ìdí nìyẹn tí a fi máa pe ẹni tí o bí ní mímọ́,+ Ọmọ Ọlọ́run.+
35 Áńgẹ́lì náà dá a lóhùn pé: “Ẹ̀mí mímọ́ máa bà lé ọ,+ agbára Ẹni Gíga Jù Lọ sì máa ṣíji bò ọ́. Ìdí nìyẹn tí a fi máa pe ẹni tí o bí ní mímọ́,+ Ọmọ Ọlọ́run.+