Máàkù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn Sadusí, tí wọ́n sọ pé kò sí àjíǹde,+ wá bi í pé:+ Lúùkù 7:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àmọ́ àwọn Farisí àti àwọn tó mọ Òfin dunjú kò ka ìmọ̀ràn* tí Ọlọ́run fún wọn sí,+ torí pé kò tíì ṣe ìrìbọmi fún wọn.)
30 Àmọ́ àwọn Farisí àti àwọn tó mọ Òfin dunjú kò ka ìmọ̀ràn* tí Ọlọ́run fún wọn sí,+ torí pé kò tíì ṣe ìrìbọmi fún wọn.)