16 Ẹ̀rù ba gbogbo wọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í yin Ọlọ́run lógo, wọ́n ní: “A ti gbé wòlíì ńlá kan dìde láàárín wa”+ àti pé, “Ọlọ́run ti yíjú sí àwọn èèyàn rẹ̀.”+
19 Ó bi wọ́n pé: “Àwọn nǹkan wo?” Wọ́n sọ fún un pé: “Àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ sí Jésù ará Násárẹ́tì,+ ẹni tó fi hàn pé wòlíì tó lágbára ni òun nínú ọ̀rọ̀ àti ìṣe níwájú Ọlọ́run àti gbogbo èèyàn;+