Mátíù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá lọ ń gbé ní ìlú kan tí à ń pè ní Násárẹ́tì,+ kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì lè ṣẹ, pé: “A máa pè é ní ará Násárẹ́tì.”*+ Mátíù 21:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn èrò náà ń sọ ṣáá pé: “Jésù nìyí, wòlíì+ tó wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì!”
23 Ó wá lọ ń gbé ní ìlú kan tí à ń pè ní Násárẹ́tì,+ kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì lè ṣẹ, pé: “A máa pè é ní ará Násárẹ́tì.”*+