ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 38:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́ inú Jèhófà ò dùn sí Éérì, àkọ́bí Júdà; torí náà, Jèhófà pa á. 8 Torí ìyẹn, Júdà sọ fún Ónánì pé: “Bá ìyàwó ẹ̀gbọ́n rẹ lò pọ̀, kí o ṣú u lópó, kí o sì mú kí ẹ̀gbọ́n+ rẹ ní ọmọ.”

  • Diutarónómì 25:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 “Tí àwọn arákùnrin bá jọ ń gbé, tí ọ̀kan nínú wọn sì kú láìní ọmọ, ìyàwó èyí tó kú kò gbọ́dọ̀ fẹ́ ẹni tí kì í ṣe mọ̀lẹ́bí ọkọ rẹ̀. Kí ẹ̀gbọ́n tàbí àbúrò ọkọ rẹ̀ lọ bá a, kó sì fi ṣe aya, kó ṣú u lópó.+ 6 Ọmọ tí obìnrin náà bá kọ́kọ́ bí á mú kí orúkọ arákùnrin rẹ̀ tó kú náà ṣì máa wà,+ kí orúkọ náà má bàa pa rẹ́ ní Ísírẹ́lì.+

  • Rúùtù 1:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ṣùgbọ́n Náómì sọ pé: “Ẹ pa dà, ẹ̀yin ọmọ mi. Kí nìdí tí ẹ ó fi bá mi lọ? Ṣé mo ṣì lè bí àwọn ọmọ tó máa fẹ́ yín ni?+

  • Rúùtù 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Dúró síbí ní alẹ́ yìí, bó bá tún ọ rà ní àárọ̀ ọ̀la, kò burú! Jẹ́ kó tún ọ rà.+ Àmọ́ bí kò bá fẹ́ tún ọ rà, bí Jèhófà ti ń bẹ, màá tún ọ rà. Torí náà, sùn síbí di àárọ̀.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́