Lúùkù 12:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ṣùgbọ́n ẹ mọ èyí, ká ní baálé ilé mọ wákàtí tí olè máa wá ni, kò ní jẹ́ kí wọ́n ráyè wọ ilé òun.+ 40 Ẹ̀yin náà, ẹ múra sílẹ̀, torí pé wákàtí tí ẹ ò rò pé ó lè jẹ́ ni Ọmọ èèyàn ń bọ̀.”+
39 Ṣùgbọ́n ẹ mọ èyí, ká ní baálé ilé mọ wákàtí tí olè máa wá ni, kò ní jẹ́ kí wọ́n ráyè wọ ilé òun.+ 40 Ẹ̀yin náà, ẹ múra sílẹ̀, torí pé wákàtí tí ẹ ò rò pé ó lè jẹ́ ni Ọmọ èèyàn ń bọ̀.”+