Mátíù 24:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 “Ṣùgbọ́n ẹ mọ ohun kan: Ká ní baálé ilé mọ ìṣọ́ tí olè ń bọ̀* ni,+ ì bá má sùn, kò sì ní jẹ́ kí wọ́n ráyè wọ ilé òun.+ 1 Tẹsalóníkà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nítorí ẹ̀yin fúnra yín mọ̀ dáadáa pé ọjọ́ Jèhófà*+ ń bọ̀ bí olè ní òru.+ 2 Pétérù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+ Ìfihàn 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Wò ó! Mò ń bọ̀ bí olè.+ Aláyọ̀ ni ẹni tó wà lójúfò,+ tó sì wọ aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,* kó má bàa rìn ní ìhòòhò, kí àwọn èèyàn sì wo ìtìjú rẹ̀.”+
43 “Ṣùgbọ́n ẹ mọ ohun kan: Ká ní baálé ilé mọ ìṣọ́ tí olè ń bọ̀* ni,+ ì bá má sùn, kò sì ní jẹ́ kí wọ́n ráyè wọ ilé òun.+
10 Àmọ́ ọjọ́ Jèhófà*+ máa dé bí olè,+ nígbà yẹn àwọn ọ̀run máa kọjá lọ+ pẹ̀lú ariwo tó rinlẹ̀,* àmọ́ àwọn ohun ìpìlẹ̀ tó gbóná janjan máa yọ́, a sì máa tú ayé àti àwọn iṣẹ́ tó wà nínú rẹ̀ síta.+
15 “Wò ó! Mò ń bọ̀ bí olè.+ Aláyọ̀ ni ẹni tó wà lójúfò,+ tó sì wọ aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,* kó má bàa rìn ní ìhòòhò, kí àwọn èèyàn sì wo ìtìjú rẹ̀.”+