Àìsáyà 53:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n sin ín* pẹ̀lú àwọn ẹni burúkú+Àti àwọn ọlọ́rọ̀,* nígbà tó kú,+Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ṣe ohunkóhun tí kò dáa,*Kò sì sí ẹ̀tàn kankan lẹ́nu rẹ̀.+
9 Wọ́n sin ín* pẹ̀lú àwọn ẹni burúkú+Àti àwọn ọlọ́rọ̀,* nígbà tó kú,+Bó tilẹ̀ jẹ́ pé kò ṣe ohunkóhun tí kò dáa,*Kò sì sí ẹ̀tàn kankan lẹ́nu rẹ̀.+