Mátíù 5:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé gbogbo ẹni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, tí kò bá jẹ́ torí ìṣekúṣe,* lè mú kí obìnrin náà ṣe àgbèrè, ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ obìnrin tí wọ́n ti kọ̀ sílẹ̀ ti ṣe àgbèrè.+ Mátíù 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, àfi tó bá jẹ́ torí ìṣekúṣe,* tó sì fẹ́ ẹlòmíì ti ṣe àgbèrè.”+ Lúùkù 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Gbogbo ẹni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, tó sì fẹ́ ẹlòmíì ti ṣe àgbèrè, ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀ ti ṣe àgbèrè.+
32 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé gbogbo ẹni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, tí kò bá jẹ́ torí ìṣekúṣe,* lè mú kí obìnrin náà ṣe àgbèrè, ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ obìnrin tí wọ́n ti kọ̀ sílẹ̀ ti ṣe àgbèrè.+
9 Mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, àfi tó bá jẹ́ torí ìṣekúṣe,* tó sì fẹ́ ẹlòmíì ti ṣe àgbèrè.”+
18 “Gbogbo ẹni tó bá kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, tó sì fẹ́ ẹlòmíì ti ṣe àgbèrè, ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kọ̀ sílẹ̀ ti ṣe àgbèrè.+