Mátíù 26:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bí wọ́n ṣe ń jẹun, Jésù mú búrẹ́dì, lẹ́yìn tó súre, ó bù ú,+ ó sì fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn, ó sọ pé: “Ẹ gbà, kí ẹ jẹ ẹ́. Èyí túmọ̀ sí ara mi.”+ Lúùkù 22:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bákan náà, ó mú búrẹ́dì,+ ó dúpẹ́, ó bù ú, ó sì fún wọn, ó ní: “Èyí túmọ̀ sí ara mi,+ tí a máa fúnni nítorí yín.+ Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+ 1 Kọ́ríńtì 11:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí ọwọ́ Olúwa ni mo ti gba èyí tí mo fi lé yín lọ́wọ́, pé Jésù Olúwa mú búrẹ́dì ní alẹ́ ọjọ́+ tí a ó dalẹ̀ rẹ̀, 24 lẹ́yìn tó dúpẹ́, ó bù ú, ó sì sọ pé: “Èyí túmọ̀ sí ara mi+ tí ó wà nítorí yín. Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+
26 Bí wọ́n ṣe ń jẹun, Jésù mú búrẹ́dì, lẹ́yìn tó súre, ó bù ú,+ ó sì fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn, ó sọ pé: “Ẹ gbà, kí ẹ jẹ ẹ́. Èyí túmọ̀ sí ara mi.”+
19 Bákan náà, ó mú búrẹ́dì,+ ó dúpẹ́, ó bù ú, ó sì fún wọn, ó ní: “Èyí túmọ̀ sí ara mi,+ tí a máa fúnni nítorí yín.+ Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+
23 Nítorí ọwọ́ Olúwa ni mo ti gba èyí tí mo fi lé yín lọ́wọ́, pé Jésù Olúwa mú búrẹ́dì ní alẹ́ ọjọ́+ tí a ó dalẹ̀ rẹ̀, 24 lẹ́yìn tó dúpẹ́, ó bù ú, ó sì sọ pé: “Èyí túmọ̀ sí ara mi+ tí ó wà nítorí yín. Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+