ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 6:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Má sì mú wa wá sínú ìdẹwò,+ ṣùgbọ́n gbà wá* lọ́wọ́ ẹni burúkú náà.’+

  • Lúùkù 11:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kí o sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jì wá,+ torí àwa náà máa ń dárí ji gbogbo ẹni tó jẹ wá ní gbèsè;+ má sì mú wa wá sínú ìdẹwò.’”+

  • Lúùkù 22:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Ó sọ fún wọn pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń sùn? Ẹ dìde, ẹ máa gbàdúrà, kí ẹ má bàa kó sínú ìdẹwò.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́