-
Ìfihàn 20:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó gbá dírágónì náà+ mú, ejò àtijọ́ náà,+ òun ni Èṣù+ àti Sátánì,+ ó sì dè é fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún. 3 Ó jù ú sínú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀ náà,+ ó tì í, ó sì gbé èdìdì lé ibi àbáwọlé rẹ̀, kó má bàa ṣi àwọn orílẹ̀-èdè lọ́nà mọ́ títí ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún náà fi máa parí. Lẹ́yìn èyí, a gbọ́dọ̀ tú u sílẹ̀ fúngbà díẹ̀.+
-