Mátíù 10:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+ Lúùkù 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe gbé ohunkóhun dání fún ìrìn àjò náà, ì báà jẹ́ ọ̀pá, àpò oúnjẹ, oúnjẹ tàbí owó;* ẹ má sì mú aṣọ méjì.*+
9 Ẹ má ṣe wá wúrà, fàdákà tàbí bàbà sínú àmùrè tí ẹ̀ ń kó owó sí,+ 10 tàbí àpò oúnjẹ fún ìrìn àjò náà tàbí aṣọ méjì,* bàtà tàbí ọ̀pá,+ torí oúnjẹ tọ́ sí òṣìṣẹ́.+
3 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe gbé ohunkóhun dání fún ìrìn àjò náà, ì báà jẹ́ ọ̀pá, àpò oúnjẹ, oúnjẹ tàbí owó;* ẹ má sì mú aṣọ méjì.*+