ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 14:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ká ní o lè fi mí pa mọ́ sínú Isà Òkú* ni,+

      Kí o fi mí pa mọ́ títí ìbínú rẹ fi máa kọjá,

      Kí o yan àkókò kan sílẹ̀ fún mi, kí o sì rántí mi!+

  • Àìsáyà 25:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó máa gbé ikú mì* títí láé,+

      Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì máa nu omijé kúrò ní ojú gbogbo èèyàn.+

      Ó máa mú ẹ̀gàn àwọn èèyàn rẹ̀ kúrò ní gbogbo ayé,

      Torí Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́.

  • Àìsáyà 26:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 “Àwọn òkú rẹ máa wà láàyè.

      Àwọn òkú mi* máa jíǹde.+

      Ẹ jí, ẹ sì kígbe ayọ̀,

      Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé inú iyẹ̀pẹ̀!+

      Torí pé ìrì yín dà bí ìrì àárọ̀,*

      Ilẹ̀ sì máa mú kí àwọn tí ikú ti pa* tún pa dà wà láàyè.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́