Sáàmù 78:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó ń rọ̀jò mánà sílẹ̀ fún wọn láti jẹ;Ó fún wọn ní ọkà ọ̀run.+ Sáàmù 105:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Wọ́n béèrè ẹran, ó sì fún wọn ní àparò;+Ó ń fi oúnjẹ láti ọ̀run tẹ́ wọn lọ́rùn.+