27 Baba mi ti fa ohun gbogbo lé mi lọ́wọ́,+ kò sì sẹ́ni tó mọ Ọmọ délẹ̀délẹ̀ àfi Baba;+ bẹ́ẹ̀ ni kò sẹ́ni tó mọ Baba délẹ̀délẹ̀ àfi Ọmọ àti ẹnikẹ́ni tí Ọmọ bá fẹ́ ṣí i payá fún.+
22 Baba mi ti fa ohun gbogbo lé mi lọ́wọ́, kò sẹ́ni tó mọ ẹni tí Ọmọ jẹ́, àfi Baba, kò sì sẹ́ni tó mọ ẹni tí Baba jẹ́, àfi Ọmọ+ àti ẹnikẹ́ni tí Ọmọ bá fẹ́ ṣí i payá fún.”+