ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 26:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Nígbà tí wọ́n ń jẹun, ó sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ọ̀kan nínú yín máa dà mí.”+

  • Máàkù 14:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Bí wọ́n sì ṣe jókòó* sídìí tábìlì, tí wọ́n ń jẹun, Jésù sọ pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ọ̀kan nínú ẹ̀yin tó ń bá mi jẹun máa dà mí.”+

  • Lúùkù 22:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Àmọ́ ẹ wò ó! ọwọ́ èmi àti ẹni tó máa dà mí jọ wà lórí tábìlì.+

  • Jòhánù 6:70
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 70 Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin méjìlá (12) yìí ni mo yàn, àbí bẹ́ẹ̀ kọ́?+ Síbẹ̀, abanijẹ́* ni ọ̀kan nínú yín.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́