-
Lúùkù 22:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Àmọ́ ẹ wò ó! ọwọ́ èmi àti ẹni tó máa dà mí jọ wà lórí tábìlì.+
-
-
Lúùkù 22:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀ láàárín ara wọn nípa ẹni tó máa ṣe èyí nínú wọn lóòótọ́.+
-