6 Nígbà tí wọn ò rí wọn, wọ́n wọ́ Jásónì àti àwọn arákùnrin kan lọ sọ́dọ̀ àwọn alákòóso ìlú, wọ́n ń pariwo pé: “Àwọn ọkùnrin tó ń dojú ilẹ̀ ayé tí à ń gbé dé ti wá síbí o,+ 7 Jásónì sì gbà wọ́n lálejò. Gbogbo àwọn ọkùnrin yìí ló ń ta ko àwọn àṣẹ Késárì, tí wọ́n ń sọ pé ọba míì wà tó ń jẹ́ Jésù.”+