-
Jẹ́nẹ́sísì 12:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí náà, Ábúrámù gbéra, bí Jèhófà ṣe sọ fún un, Lọ́ọ̀tì sì bá a lọ. Ẹni ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75) ni Ábúrámù nígbà tó kúrò ní Háránì.+ 5 Ábúrámù mú Sáráì+ ìyàwó rẹ̀ àti Lọ́ọ̀tì ọmọ arákùnrin rẹ̀,+ ó kó gbogbo ẹrù tí wọ́n ti ní+ àti àwọn èèyàn* tó jẹ́ tiwọn ní Háránì, wọ́n sì forí lé ilẹ̀ Kénáánì.+ Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Kénáánì,
-