Ìṣe 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìkà sí ìjọ. Bó ṣe ń jáde nínú ilé kan ló ń wọ òmíì, ó ń wọ́ tọkùnrin tobìnrin jáde, ó sì ń jù wọ́n sẹ́wọ̀n.+ Gálátíà 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ ti gbọ́ nípa ìwà mi tẹ́lẹ̀ nínú Ìsìn Àwọn Júù,+ pé mò ń ṣe inúnibíni tó gbóná* sí ìjọ Ọlọ́run, mo sì ń dà á rú;+ Gálátíà 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Wọ́n kàn máa ń gbọ́ pé: “Ọkùnrin tó ń ṣe inúnibíni sí wa tẹ́lẹ̀+ ti ń kéde ìhìn rere nípa ẹ̀sìn* tí òun fúnra rẹ̀ ń gbógun tì tẹ́lẹ̀.”+
3 Ṣùgbọ́n Sọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀ sí í hùwà ìkà sí ìjọ. Bó ṣe ń jáde nínú ilé kan ló ń wọ òmíì, ó ń wọ́ tọkùnrin tobìnrin jáde, ó sì ń jù wọ́n sẹ́wọ̀n.+
13 Ẹ ti gbọ́ nípa ìwà mi tẹ́lẹ̀ nínú Ìsìn Àwọn Júù,+ pé mò ń ṣe inúnibíni tó gbóná* sí ìjọ Ọlọ́run, mo sì ń dà á rú;+
23 Wọ́n kàn máa ń gbọ́ pé: “Ọkùnrin tó ń ṣe inúnibíni sí wa tẹ́lẹ̀+ ti ń kéde ìhìn rere nípa ẹ̀sìn* tí òun fúnra rẹ̀ ń gbógun tì tẹ́lẹ̀.”+