11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín.
16 Jòhánù dá wọn lóhùn, ó sọ fún gbogbo wọn pé: “Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín, àmọ́ ẹni tó lágbára jù mí lọ ń bọ̀, ẹni tí mi ò tó tú okùn bàtà rẹ̀.+ Ó máa fi ẹ̀mí mímọ́ àti iná batisí yín.+