ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 2:47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 wọ́n ń yin Ọlọ́run, wọ́n sì ń rí ojú rere lọ́dọ̀ gbogbo èèyàn. Lẹ́sẹ̀ kan náà, Jèhófà* ń mú kí àwọn tó ń rí ìgbàlà dara pọ̀ mọ́ wọn lójoojúmọ́.+

  • Ìṣe 4:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ lára àwọn tó gbọ́ ọ̀rọ̀ wọn di onígbàgbọ́, iye àwọn ọkùnrin náà sì di nǹkan bí ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000).+

  • Ìṣe 5:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ṣe ni àwọn onígbàgbọ́ nínú Olúwa ń dara pọ̀ mọ́ wọn, iye wọn sì pọ̀ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.+

  • Ìṣe 9:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ní tòótọ́, nígbà náà, ìjọ tó wà jákèjádò Jùdíà àti Gálílì àti Samáríà+ wọnú àkókò àlàáfíà, à ń gbé e ró; ó ń gbèrú sí i bó ṣe ń rìn nínú ìbẹ̀rù Jèhófà* àti nínú ìtùnú ẹ̀mí mímọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́