ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 ẹ wá pa Olórí Aṣojú ìyè.+ Àmọ́ Ọlọ́run gbé e dìde kúrò nínú ikú, òtítọ́ yìí ni àwa ń jẹ́rìí sí.+

  • Róòmù 4:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 àmọ́ ó jẹ́ nítorí wa pẹ̀lú, àwa tí a máa kà sí olódodo, nítorí a nígbàgbọ́ nínú Ẹni tó gbé Jésù Olúwa wa dìde kúrò nínú ikú.+

  • 1 Kọ́ríńtì 6:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àmọ́ Ọlọ́run gbé Olúwa dìde,+ yóò sì gbé àwa náà dìde kúrò nínú ikú+ nípasẹ̀ agbára rẹ̀.+

  • Kólósè 2:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 A sin yín pẹ̀lú rẹ̀ nínú ìbatisí rẹ̀,+ àjọṣe tí ẹ sì ní pẹ̀lú rẹ̀ mú kí a gbé ẹ̀yin náà dìde+ pẹ̀lú rẹ̀ nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ yín nínú iṣẹ́ agbára Ọlọ́run, ẹni tó gbé e dìde kúrò nínú ikú.+

  • Hébérù 13:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Kí Ọlọ́run àlàáfíà, tó jí Jésù Olúwa wa dìde, olùṣọ́ àgùntàn ńlá+ fún àwọn àgùntàn, pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú àìnípẹ̀kun,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́